Home / Art / Àṣà Oòduà / E wo aso Ebuka níbi ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti ìyàwó rè, Adesua Etomi.

E wo aso Ebuka níbi ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti ìyàwó rè, Adesua Etomi.

Òpò ni ara ti n yá tí won sì ti fi ojú s’ónà láti wo aso tí Ebuka ma wò ní òtè yí báwo ni ó ti è se ma rí nínú rè ni ìbéèrè àwon ènìyàn, bí ó tilè jé wípé, ó ti da orí èro ayélujára rú látàrí Agbádá nlá tí ó wò lo sí ibi ìgbéyàwó ìbílè won.
Ó kan rora pín àwòrán aso tí ó wò ni àwon olólùfé rè bá bèrè sí ní ma sòrò nítorí wón fé.jù béè lo, sùgbón ó kúlú rewà nínú rè.

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

policeman

Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure

Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...