Home / Art / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908
ilu belgium

E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908

Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to daju ju lo, ilu Belgium lakoko, ilu to sikeji ni Jamani.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti