Gégé bí a ti mo wípé òkan gbógì ní ilé-èkó gíga Òbafemi Awolowo University (OAU) jé ní orílè èdè Nìjíríà yí.
Sà déédéé ni a gbó wípé arábìnrin kan tí ó jé akékòó ilé-èkó yí ya wèrè látàrí ìwé kíkà nígbá yí ó jé wípé ìdánwò won ti kù sí dèdè.
Ní alé ìjeta ni ìsèlè yí selè, nígbá tí omobìnrin yí sa wèrè tán, ìwé tí ó n kà náà ló fi ñ lu ìlù. Àfi kí elédùà gbàwá ooo.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

