Home / Art / Àṣà Oòduà / Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?
ijapa

Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?

Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa.
Ibeere
talo daran egbaafa ninu awon mejeji ??
Aku ojumo gbogbo omo kootu aji ire bi
aku faaji opin ose, mo ro wa eje ki a se jeje nitori igi iberu ni tojo
IRE O O O O O

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti