Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o
Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.)
Iye eni kokan wa koni ra ooo
Ejowo ooo
Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to nko enu ife si ohun ejowo too
Kin ni itumo ala bee ooo
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

