Oruko mi ni IBINU, emi ko le fun wara, sugbon mo le da wara nu.
Ise ti eniyan ba fi ogun odun ko jo, emi IBINU le fi iseju kan baaje.
Sora fun emi IBINU ti o ba fe se ohun rere nile aye.
Inu bibi eru ni n pa eru; edo fufu iwofa lo n pa iwofa; emi IBINU lo n je bee.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

