Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé won bí won fún ara won ni, won bí won láti níìfé ara won ni, nítorí náà ìfé tí won ti ní síra ti pòjù.
Banky W tí ó pín àwòrán kan náà ti se ìlérí láti níìfé rè títí di ojó ogbó.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

