Home / Art / Àṣà Oòduà / Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu
Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan si n yo ijoba ipinle Eko lenu pe ki o ti gbogbo ilu pa lo le segun arun naa daadaa. Sanwo-Olu da won lohun pe arun naa ko ti ran de iye to le mu ki ijoba ti gbogbo Eko nitori ipo ti ipinle naa wa ni orileede yii. Gomina Sanwo-Olu tun salaye awon to maa letoo si ounje ofe. O ni awon ti eya ara pe nija ati awon arugbo ni eto naa koko wa fun bayii. O ni bi agbara ba se n de sii ni o maa so bi awon se maa te siwaju nipa iranlowo naa. Bayii eniyan aadorin (70) lo ti ko arun buruku naa ti merinlelogoji (44) si sele ni ipinle Eko. Ki Eledua ba wa segun ajakale arun naa.

Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu

Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.
Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.
Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa maa pe emi ni “Mr Governor “.
Gomina ni iwe iso-di-ooto re gan-an maa jade ni ola, ojo keje, osu ti a wa ninu re yii.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb