Home / Art / Àṣà Oòduà / Emma Nyra dùn nínú aso ìwè tí ó wò ní Dubai .

Emma Nyra dùn nínú aso ìwè tí ó wò ní Dubai .

    Olórin orílè èdè Nàíjíríà, Emma Nyra ti gbìmò láti fi èbùn tí olórun fun han gbogbo àgbáyé lórí èro ayélujára ( Instagram).

Olórin tí ó n lo ìsinmi rè lówó ní Dubai ti pín àwòrán tí ó yà lébàá òkun, èyí tí ó fi èbùn tí olórun ní ara rè hàn.
Àwò rè sì rí bí ti omo tuntun.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti