Àwon Òrìshà, Yemoja, Oya, Òshun, Elégba àti òshóòsì jé àwon Òrìshà tí ó dúró fún èdá ènìyàn ní gbogbo ònà, tí won sì máa ń wá sí ayé gbangba. Nígbà tí akoni wa òshóòsì, tí ó jé ògbójú ode, tí ó sì jé alágbára okùnrin, tí gbogbo èròńgbà rè jé láti lo pèlú àwon Òrìshà tó kùn, a rán an láti wá wú Òrìshà Elégba lórí, Òrìshà tí ó jé Òrìshà oríta méta : Òrìshà oríre sùgbón tí ó tún jé Òrìshà jàmbá, tí ó máa gbe lo sí iwájú baba wa olódùmarè.
Wá èbùn tí ó tó fún Elégba kí o sì gbe fun ní ojú àwon ènìyàn? Kò sí wàhálà – àbí ohun tí òshóòsì rò ni. Sùgbón èrò yí ńlépa èbùn ńlá yí, e wá jé kí á wò ó, ó le è padà di ònà àjálù.
Ìrújú òtító tí ó jé wákàtí ònà tààrà, ìsodi arìndìn eré síso ìtàn. Ìtàn ayé àwon Òrìshà wònyí ti yí papò mó ìtàn ayé omonìyàn. Ìtàn tí ó l’ágbára tí Menzies so, tí ó so ìtàn ìgbésí ayé ènìyàn ní òkòòkan ní sísè n tèlé . Jíjó dáadáa rè túmò sí ohun tí Òrìshà kòòkan ní, láti ibi tí ó le , tí ó so ohun tí Òrìshà kòòkan ní bí Oya, Òrìshà aféfé àti ìjì, títí dé orí Òrìshà odò, Òshun, olorì ìgbádùn, ìdùnú, ìbálòpò àti síse abiyamo, tí ó ló ònà rè sí òdò rè…