Home / Art / Àṣà Oòduà / Ẹ̀yẹ̀lé
eyele

Ẹ̀yẹ̀lé

Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, 
Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, 
Rirọ lonrọ àdábà lọrún, 
Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀, 
Tùtù ni omi àfi owúrọ̀ pònri, 
Ao ni mo inira layé ti àwá, 
Alanú kàn toju igba àlànú lọ, 
Yio wa wari, 
Mogbà làdúrà pe oké ti àwá ao ni jabọ, 
Ninu ọsẹ̀ yi ao ri owún tọkàsi ni rèrè, 
LAGBARA OLODÚMÀRÉ ỌBA TODA AYE TOFIFUN ỌRÚNMILA,

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti