Gbajúgbajà òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà, Funke Akindele ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tuntun ti ara rè tí ó sèsè yà níbi tí ó ti padà sí enu isé.
Sùgbón ìbéèrè ni wípé, sé ó ti bímo ni àbí báwo?
Níbi àwòrán tí ó pín, n se ni ó dàbí eni wípé ó ti Sanra si, súgbón mi ò rí oyún ní ikùn rè.
Mo rò wípé kì í se nkan tí mò n rò sha? àbí sé ohun tí mò n rò ni èyin náà n rò ni?
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

