Gbajúgbajà òsèré, Joke Silver so wípé nse ni olóògbé E.A Silver àti Dr.Abimbola Silver gba òun tó ni sùgbón nse ni kìí se wípé òun kò mò télè .
Joke Silver so wípé nígbà tí ó yá ni oko òun mò wípé won gba òun tó ni.
Bí ó tilè jé wípé won gba mama tó ni baba kò saláì má n’ífè rè béè.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

