Home / Art / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè
Diamond Platnumz

Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè

Gbajúgbajà olórin ní ìlà oorùn adúláwò tí a mò si Diamond platnumz ti yanjú aáwò tí ó wà láàrin òhun àti ìyá omo rè léyìn wákàtí tí ó bá a wí fún àìso òtító . Ó pín eré oníse amóhùn máwòrán (video) tí òhun àti omo àti ìyá omo rè hàn nínú è “mo ti sòrò ” won jùmò pa ohun tí won fi sí orí aféfé ré. Ó tún pín eré obese amóhùn máwòrán òhun àti Zari pèlú àwon omo won tí won ń seré pèlú ohun tí a mò sí “yà  ko  tè “(snapchat)…….

English Version

Continue after the page break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti