Yorùbá Dùn shared the following link and had this to say about it: Oloorun ni omo naa, ko fe ki won ba fohin re lero ni won ba mu lele fun un. Nje ohun to buru wa ninu igbese ti won gbe yii? E dahun awon eniyan wa nibi:
Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...