Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.
Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC fún ìdìbó ti odún 2018 ní ìpínlè Osun, ìpínlè omolúàbí.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

