
Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó náà kí ó tó di wípé ìjambá náa selè tí ó dì kò kalè láti ràn wón lówó. Ìjàmbá okò yí selè ní òpin Ibadan ní ìyànà Sagamu.
Ní òpópónà Ibadan sí Ekoní ìpínlè Ògún ní agogo méjìlà àbò òsán.
Oyetola nígbà tí ó débè ó jáde kúrò nínú okò rè láti ran awon tí ìsèlè yí selè sí lówó.
Oyetola tún gbìyànjú báwon pe ilé-ìwòsàn ní kíákíá.
Ìjàmba yí selè láàrin oko Toyota Corolla fúdú ati okò elérò méjìlá. Won ni oko elérò yí ti tàkìtì láìmoye ìgbà nígba tí ó tí so owó okò nù.
Bí ó tilè je wípé bí ó se selè pò ju báyìí lo súgbón èyí tí a rígbó nìyí.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

