Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì). Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde (Electronic media), Simeon Nwakaudu. Wike so wípé ìdádúró náà esèkesè ni; ó so fún Harrison kí ó gbé ipò fún Akòwé pípé nínú àkóso náà. Kò sí ìdí kan pàtàkì tí won fi lé Konmisônna na níbi isé….
English Translation
Continue after the page break
Pages: 1 2
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

