Home / Art / Àṣà Oòduà / Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà.

Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà.

Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà.

Ìyáawa Grace Atinuke, tí won bí ní ojó kerìndínlógún osù beelu ní odún 1931, tí a mò sí eni tí ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà ní odún 1952.

Lóòtó ìlú Kogi ní won tí bí màmá, ìyáawa oyelude ni a bí sí ilé Kano sí ìdílé James Adeleye Olude àti Marthan Dantu tí àwon méjèèjì jé omo bíbí Isanlu, tí a mò sí ìpínlè Kogi báyìí.

Arewà ni ìyá ní tòótó e wo bí won se tún re wà.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti