Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.

Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.

Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am).

Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ìkan jé omo bíbí inú ìlú náà tí a mò pèlú ìnagije rè “Aníní “ti àwon méji tí ó kùn rè wá láti Vandeikya ní ìjoba ìbílè náà tí won yin ìbon pa wón nígbà tí won jo ń yin ìbon mó ra won pèlú àwon Joint Task Force.

Àwon adigunjalè yí ti wo ilé tí ó pò tí won sì gba owó àti èro ìbánisòrò won lo tí a sì ti gbà á padà lówó won, bákan náà ògá àwon adigunjalè yí bó tí a kò sì mo ibi tí ó wà

Continue after the page break for English Version

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti