Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìgbà èdá

Ìgbà èdá

Ìgbà kò lo bí òréré
Ayé kò lo bí òpá ìbon,
Ìgbà kan ńlo
Ìgbà kan ńbo
Kí elédùmarè jé kí á n’ígbà tó dára n’ílé ayé wa

Ìgbà kan ni ogún náírà yí níyì púpò
Sùgbón nísìnín
Ó ti di ohun tí èèyàn ò fé rí mo.

Ìgbà rere ni kí á ma toro
Kí elédùmarè fún wa ní ìgbà òtun.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti