Bi Eledumare ba ran eda lowo, bi idan ni i ri. Majek Fashek ti opolopo sebi o ti tan fun latari bi okunrin naa se fi ogun oloro baye ara re je, ti ko si ni kobo lowo mo lati fi jeun. Okunrin olowo kan ninu Warri, Ayiri Emami ni Oba oke ran si i. O fi owo se itoju re, okunrin olorin naa si pada bo si po pada. Majek Fashek re e nibi o ti n korin nibi ayeye ti won se lati fi bu ola fun oloogbe Fela Kuti, Felabration.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more



