Home / News From Nigeria / Breaking News / Ìjàmbá ńlá okò kan tí ó ń jé Nissan Rogue selè ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge).

Ìjàmbá ńlá okò kan tí ó ń jé Nissan Rogue selè ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge).

Okò tí ó ń jé Nissan Rogue àti Toyota Dyna kolu ara won ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge) ósì dà bí eni wípé okò Nissan Rogue náà wón ju iye tí won na lò. Àwon LRU ti gbe àwon okò náà kúrò lésèkesè…­

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti