Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.
kai

Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.

Ìjoba ìpínlè Èkó, lábé àse Gómìnà, láti jé kí ìlosíwájú bá ètò ìlera ti dá àwon òsìsé KAI (kick against indiscipline) dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.

Ìgbésè náà, gégé bí ìjoba ìpínlè náà, jé òkan lára ìsàkóso àwon ohun ègbin ní ìpínlè náà.

Nígbà tí ó ń sòrò níbi tí won ti fi CLI ló’lè ní gbàgede Agege (Agege Stadium), Èkó, Gómìnà ìpínlè náà, Akinwumi Ambode, Láàná, so pé ìgbésè náà mú ìdàgbàsókè bá ìmótótó ojóòla, ìlera àti àyíká tí kò ní àgbàrá.

Gómìnà, tí igbákejì rè s’ojú, MRS. Idiat Adebule, so wípé ètò náà jé àtúnse olópé pípé tí won farabàlè s’ètò láti kojú àwon kùdìèkudie tí ó ń kojú ìsàkóso ìpínlè náà .

Bí ó ti rí náà, gbígbá ègbin láti ojúlé dé ojúlé àti ònà láti gbe lo sí ibi tí a ń da ègbin sí (multinational waste service company) ni àti fún won ní ibìkan láti yálò pèlú irinsé tuntun tí ó máa ń ki ìdòtí m’ólè tí ó tó 600 pèlú egbèrún lónà èédégbèrún (900,000) irinsé ibi tí won ń d’alè sí tí ó jé ti Iná, tí ó jé wípé àwon ègbin tí ilé-isé bá se àwon License waste operator (PSP) ni yóò kojú rè.

Gégé bí omo oòduà rere se so, Komísónà tí ó ń mójú tó àyíká, Mr. Babatunde Adejare so di mímò wípé àwon àgùnbánirò tí ó to 920 wà ní LAGESC, èròjà gbígbá ègbin inú omi àti ìgbálè oníná ti jé àlá àríwòye tí ó wá sí ìmúse nínú ètò àyíká tuntun, bí ó se fowó s’òyà wípé ìdàgbàsókè náà ma so èso rere látàrí mímú ìdàgbàsókè bá ètò ìlera àti mímú ayé rorùn fún àwon olùgbé ìpínlè náà.

Ó tún kéde pé Gómìnà ìpínlè náà yó fi àwon eka òsìsé CLI, míràn sílè bíi gbígbá ègbin ojúlé sí ojúlé, òwò, ilé-isé àti gbí gbé ogun ti ohun k’óhun lórí omi adágún…….

Continue after the page break for English Translation

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo

#Masoyinbo Episode Seventy-three: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture