Mejeeji ko papo amoo won maa n wo tele ara wo leyin ni. Yorubo won ni, ikoja aaye nii mu ki fulani o kiri odo iyan. Aimo iwon ara eni naa nii sii muki abuke o ko ise atun’ko se. Emo je ki a koja aaye wa, ki a si mo se ju agbara wa lo..
Mary Fágbohùn Gbajugbaja olorin Naijiria, Keshinro Ololade, ti gbogbo eniyan mọ si Lil Kesh, ti sọrọ nipa didi olokiki bi ọdọmọkunrin. Olorin ‘Young And Getting It’ ṣàlàyé pé ṣíṣe àṣeyọrí ní kékeré jẹ́ “eru wuwo.” Lil Kesh ṣe ifihan eyi lori eto Esther laipẹ yi, eyi ti o gbe jade lori YouTube ni ọjọ keji osu karun-un, Ọdun 2025. Ó sọ pé: “Bí mo ṣe tètè di olokiki da bii eru wuwo. Mo di olokiki ni omode. Omo ọdún mọ́kàndínlógún ...