Home / Art / Àṣà Oòduà / Ikún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin yí ni ó gba orí ìbùsún ya wèrè.

Ikún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin yí ni ó gba orí ìbùsún ya wèrè.

Ìròyìn jé kí á mò wípé arábìnrin yí ya wèrè léyìn tí eni tí ó ti láya nílé ba lájosepò tán. Gégé bí eni tí ó sún mo se so. Ó so wípé ó ti mo omobìnrin yí lára kí ó má bá oko olóko sún kiri, tí ó sì jé wípé àwon kìlò fun tó, ohun tí ó máa n so ni wípé sebí ayé òun ni, àti wípé ohun tí ó ba wu òhun ni òhun le fi ayé òhun se, kò kan eni kéni.
Ó ti wá kan èèyàn báyìí oooo, kí á ya sóra.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti