Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí .
Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà tí okò tí a mò sí Lexus jeep, epo beetíròlù yí dànù arábìnrin yí sì jóná di eérú.
Olórun, olódùmarè dárí jìwá ní orílè èdè yí..
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

