Home / Art / Àṣà Oòduà / Itunmo Ala wipe Olopa mu yin.
olopa

Itunmo Ala wipe Olopa mu yin.

Bio Bala alawipe loju orun olopa mue waa bo ninu ewu tio
koju dae sungbon ti olopa ba mue tio fi handcuff sie lowo
Oranla Kan nbo wa fune AFOWOFA arare ni yio si da oran
naa sie Lorun kio yara tete mura kio tera mo adua daada
pelu aawe bakan naa ti olopa bamu e ti won tie mole Cell,
Sora daada fun oore aseju kio Ma ko bae

 

 

 

Bio Bala alawipe loju orun oun gbale boya iwo nikan ni tabi
epo ala ikilo ni alayi Lasiko tio la alayi ogbodo Jina si ibinu
kio si Ma ba Eniyan ja nitori bio bajare iwo ni aye o pada da
lebi sungbon tio bale se suuru daada oore nla bowa fune
lati ibiti iwo Koro okan ire

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti