iwa

Iwa Dabi Eyin

Toju iwa re iwo ore mi.
Maa ranti wipe iwa-lewa.
Ewa bii iwa ko si.
Bi o ba dara bii egbin.
Ti o tun rewa bi okin.
Eran ikan ni lojo tiku ba de.
Sugbon iwa lohun ti kii ku.
…….
E kaale o, Edumare ko ni je ka seru aye; iwa wa ko ni so wa di ero eyin o(Ase).

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.