E MAA WI TELE MI :
Ire ayo ni temi losu yii.
Ire idunnu ni temi losu yii.
Ire owo ni temi losu yii.
Edumare foro mi se’yanu lose yii.
Igbega ati aseyori ni temi.
Osu yii yoo san mi si rere.
Akoba, adaba ko ni je temi(Ase)
Aare Olasunkanmi Alani Agbasaga
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

