E MAA WI TELE MI :
…………….
*Edumare ma je ki n f’ewon logba.
*Oluwa gba eru iya lorii mi.
*Edumare ma se je ki n seru egbe.
*Eledumare taari alaaanu si mi.
*Edumare fisoo re so mi.
*Eledua pase irorun sinu ayee mi.
*Iku aitojo ko ni pa mi(Ase).
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

