Home / Art / Àṣà Oòduà / Iwure Owuro: 08.05.2016

Iwure Owuro: 08.05.2016

E MAA WI TELE MI :
……..
*Oluwa gba eru iya lori mi.
*Edumare ma se je ki n seru egbe.
*Oluwa taari alaanu si mi.
*Edumare fiso re so mi.
*Oluwa pase irorun sinu aye mi.
*Iku aitojo ko ni pa mi(Ase).
………
E ku ojulona sinima ‪#‎ORISUN_OLA‬ latowoo King Ogulutu Oro.
……………..
E KU OJULONA # IBILE_FESTIVAL_ SEASON1.
……….
Ilu ibile.
Ijo ibile.
Orin ibile (Ewi, Ijaala, Esa).
Iwosan ibile.
Ounje ibile.
Aso ibile.
# IBILE2016
……..
Lati fi oruko sile ati
fun ekunrere alaye : +2347031174331.
+2347062422360.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti