Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀dí
Orí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀dí
Olú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀dí
Nítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ
Mo sé ní iwure fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ire tí kálukú wa bá kójọ kò ní pẹ̀dí mọ́ wa lọ́wọ́ o láṣẹ Olódùmarè. Àsẹ
Pages: 1 2
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

