Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró.
Kí Elédùmarè gbà wá lówó won.
Posted by: Awoyemi Bamimore in Àṣà Oòduà, Breaking News Comments Off on Ìyà tí òyìnbó fi je ìran Yorùbá kò kéré.
Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró.
Kí Elédùmarè gbà wá lówó won.
Tagged with: Àṣà Yorùbá