Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won.
Ó ko síbè wípé.
“A le fi tipátipá mú Esin lo sí odò sùgbón a kò le fi tipátipá fun lómi mú”.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

