Home / Art / Àṣà Oòduà / Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.

Linda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.

Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce.

Ó ko síbè wípé…
“Mo gbàdúrà wípé kí gbogbo obìnrin di abiyamo…kò sí ayo tí ó tó èyí”.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti