Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni won ti gbé lo sí ilé ejó .
Won fi èsùn kàn wípé ó pa oko rè. Maryam kò le mú òrò náà móra ni ó bá bú sígbe gbàmù nígbà tí ó dì mó omo rè osù méfà móra.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

