Ògá àkójopò HKN, Davido, tí ó pe ìkan lára àwon olólùfé rè obìnrin jáde, Sheilah Parker, tí ó gbe lo sí orí èro ayélujàra (snapchat ) láti p’aró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò pèlú arabìnrin náà. Olórin tí ó bèèrè wípé “Kílódé tí àwon ènìyàn fi rí báyìí? Ó tún jé kí won mò wípé òun kò ní dá àwon DMs lóhùn mó.
Àwòrán nìyí n’ísàlè….
 
		 Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more