Home / Art / Àṣà Oòduà / “Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .

“Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .

     Òkan lára àwon Olólùfé obìnrin tí ó ti nífèé Wizkid ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi èhónu rè hàn wípé òun nífèé Wizkid sùgbón ó so wípé ànfààní nlá ni kí Wizkid fé òun kí ó sì já òun kulè. Nígbà tí Wizkid yóò fèsì lórí èro ayárabíàsá tí ó ro arábìnrin yí kí ó má se nífèé òun rárá nítorí òun ma ja kulè.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti