“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.
Gbajúgbajà àti ogbóntarìgì olórin tí a mò sí Burna Boy nse ni ó dàbí eni wípé ó ti rí àyànfé, ó pín àwòrán tí won dì mó ara won, bí ó tilè jé wípé a kò mo arábìnrin arewà yí.
Ó pín àwòrán náà pèlú òrò tí ó ya ni lénu.
E wo àwòrán náà.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


