Home / Art / Àṣà Oòduà / Musa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.
musa musa

Musa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.

Àwon Agbófinró ti rí àwòrán olóòpá kan tí ó jé atónà fún àwon ìgárá olóshà tí ó fó ilé Ààre télè Goodluck Jonathan ní Gwarimpa Abuja.

Musa tí a gbé lo sí ilé-ejó gíga díè (magistrate) ní ojó ìségun tí won sì dá sílè pèlú Mílíònù Méje (7 million) pèlú eni tí ó dúró fun tí ó jé òsìsé ìjoba àti olùgbé Abuja.

Àwon àwòrán tí won yà ní agbègbè ilé-ejó lónìí…

Continue after the page break for English Version

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti