Home / Art / Àṣà Oòduà / Ni oni tise ọjọ aje emi ati iwọ amari tiaje se !

Ni oni tise ọjọ aje emi ati iwọ amari tiaje se !

Aje rere awole tọ ẹni kankan wa wáa….owo ayọ ni ama pajale ose..a oni pawo ẹjọ,wahala,isan,ibanuje .owo ayọ ni mapa…igi aje amaso nile oluka lukuwa…ase…ifakanso ni odu e bayi wipe……

Arakoko ki adifa fun wọn nilu ọwọlọ eyiti igi aje nso leyin kulẹ̀ wọn(wọn niki won karanle ẹbọ niki wonse).

Orunmila ni owa jawaja ifa moni owa jawaja……
Ọwa jaja waja ni igi aje gben nso niku awo…
ojo_aje_1

Igi aje toso sile emi ati iwo arakoni bẹ danu…..ase,,ase,,,ase,,

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

general

Army General Expose the Foreign Missions Behind Boko Haram And Bandits In Nigeria