Kò tirẹ̀ lápátí
Kò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun
Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ àti ẹbí àti ará wa nígbà kankan. Àsẹ
Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...