Home / Art / Àṣà Oòduà / Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Oba Aworeni Makonranwale Adisa ti re ìwàlè àsà, baba ti lo bá àwon baba ńlá rè.

Olúsèse, Àràbà àgbáyé ti dágbére wípé Ó dígbà fún aráyé, baba ti lo rè é bá àwon baba ńlá rè ní ìwàlè àsà.

Ó mà se oo, ikú ti pa agbe kò le dáró, ó ti pa àlùkò kò le ko sùn, ikú ti pa lékélèké kò le k’efun, baba wa Olúsèse ti lo.

Àrólé òrúnmìlà se béè ó ròrun Alákeji, awo ooni Olódù mérìndínlógún se elèdè léyìn baba.

Omo Oòduà rere ń se elédè léyìn baba….

 

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti