Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. sun reeooooo.
Long ago, in the ancient city of Ibadan, famed for its warriors and sprawling hills, there lived a gatekeeper-warrior stationed in the outskirts of the city, in a settlement known as Lálúpọn on the way to Ìwó. His duty was clear: to watch the road, collect tolls, and guard the passage of traders and travellers entering and leaving Ibadan. Because of this important task, people called him Oníbodè Lálúpọn; the Gatekeeper of Lálúpọn. Though he was not particularly comely, Oníbodè ...