Home / Art / Àṣà Oòduà / Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.

Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.

Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November 19) léyìn àìsàn kékeré tí ó se é nígbà tí ó n sin ìjoba ní Makurdi ní ìpínlè Borno. Won ti sin-ín láàná ní ìpínlè River. Kí olúwa te sí aféfé rere.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti