Home / Art / Àṣà Oòduà / Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

    Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?.

Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

Olórin ìgbàlódé kan tí ó n jé Runtown tí orúko rè gangan n jé (Douglas Jack Agu ) ní ègbé òdóbìnrin yí ni àwòrán okùnrin yí n hàn.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti