Àwon òlùgbógunti Adigunjalè ti ìpín Okehi ní ìpínlè River ni owó won te òdómokùnrin kan tí ó ń jé Emeka Nwala tí ó jé odún méèdógbòn (25years) àti òdómokùnrin Otamasiri Onyesu tí ó jé odún mókàndílógún. Tí won sì fi èsùn kan wón wípé àwon ni won jí olóyè pàtàkì kan gbé ní ìlú Umuehem tí won jí gbé pa mó fún òpòlopò ojó.
Àwon ìgbìmò oníwà rere ìlú ni ó s’ètò bí won se rí won mú nípa gbígbá rùkù ti àwon olóòpá púpò. Won ń ran àwon olóòpá lówó láti gbé won lo sí ilé-ejó láìpé…
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

