Home / Art / Àṣà Oòduà / Ojuitere ooooooo!!
aso iyi ile yoruba

Ojuitere ooooooo!!

mo de werewere bi eji-ale mo
de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke
tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe
enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi
pakute mu eja l’odo, beni omode koni si
owo lu labelabe, toripe bi igbin ba su yo fi
aya ko bi ijapa ba su yo fi aya ko, ojulu ma
segun ota ma reyin odi, o ya eyin te laye e bami
fi ase si toripe aba ti alagemo ba da oun ni
orisa oke gba, atipe ati eru ati omo won ki
binu owo, bi alagemo ba yo si oju-agbo yo
di orisa apewo, afin o ni wo oja ki ero-oja
sope oun o ri, toripe obinrin koni ri nkan-
osu(mensuration) ko wa yan l’odi. atipe won
ki fi aja bo yemoja, won ki fi obi-abata bo
sango enikan ki gboju le ogun titi kowa fi
igi-awusa da ‘nan, eyin agbalagba te l’aye eyin ti
edua yonda aye fun e ma womi niran se keba mi fi
ase si, kin mafi ese ati enu ko lowo awon
ajunilo orewa toripe iwo nan bami se Ase
oun ti aye kofi le e lowo won o ni bere
lowo re

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti