Bàbá bàbá kan tí ó jé bàbá orílè èdè Nàìjíríà àti ìyá ìyá ni won se ayeye ojó ìbí fún nígbà tí won pé ogóòrún àti márùndínlógóòrún. Gégé bí olùsòrò kan lórí èro ayélujára se so àti olùsòrò gbogbogbò tí a mò sí Chris Ogedengbe. Àwon tokotayà yí tí mùsèmúsè won tún gbá músémúsé, tí won sì tún le rìn, lo sí ilé-ìjosìn àti wípé ìyá tún se óúnje fún bàbá (oko rè). Àwa náà ki yín kú ojó ìbí o tokotayà .
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

